Bí Idaraya Ẹmí ṣe lè rí ni oríṣiríṣi. Ó sábà máa ń nípa ìrọ̀rùn orin Mantra àti ìmúmú ìmòran-inu (visualization).
A gbà àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Eckankar níyànjú láti lo ìṣẹ́jú mẹ́ẹ̀dógún sí ogún (15 sí 20) ní gbogbo ọjọ́ nínú ìrònú (contemplation) gẹ́gẹ́ bí Idaraya Ẹmí.
Ó dára jù láti ṣe idaraya náà ní àkókò kan náà àti ní ibi kan náà, ní gbogbo ọjọ́.
Awọn ohun elo
Láti kẹ́kọ̀ọ́ sí i nípa kókó yìí kí o sì rí àkójọ ni kikun ti àwọn idaraya ẹ̀mí, jọ̀wọ́ ka “The Spiritual Exercises of Eck” nípa Sri Harold Klemp.