Sugmad ni orúkọ Ọlọ́run ní Eckankar. *IT* wà ní ìkọjá àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀ ayé, nínú Òkun Ìfẹ́ àti àánú.
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìfarahàn Sugmad wà nínú àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀ ayé tó ní àṣẹ-ìjọba tiwọn àti àwọn orúkọ tirẹ̀.
Àwọn ọ̀pọ̀ irú ẹ̀dá tún wà nínú àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀ isalẹ tí ó fi ara wọn hàn bí Ọlọ́run.
Awọn ohun èlò
- Wo chart of God Worlds and Lower Worlds lórí ojú ìwé 338 ti Eckopedia, The Eckankar Lexicon.
- Tiger's Fang, nípa Paul Twitchell