Marpa jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olùkọ́ ẹ̀mí ti Eckankar, tí a mọ̀ sí ECK Masters. Ó kọ́ àwọn ẹ̀kọ́ ECK ní Tibet. Milarepa jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀.
Àwọn ohun èlò ìtọ́kasí
- Àlàyé síi wà fún ọkọọkan àwọn ECK Masters nínú Eckopedia, The Eckankar Lexicon.