Baraka Bashad jẹ́ ọ̀rọ̀ ìfarahàn tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ Eckankar máa ń lò tí ó túmọ̀ sí “Kí ìbùkún rí”.
Ó tún jẹ́ ọ̀nà mìíràn láti sọ “Ìfẹ́ Rẹ́ kí ó ṣẹ”.